Eksodu 25:4
Exodus 25:4 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
aṣọ aláró, elése àlùkò, òdòdó, ọ̀gbọ̀; irun ewúrẹ́.
Exodus 25:4 in English
Exodus 25:4 · Berean Standard Bible
blue, purple, and scarlet yarn; fine linen and goat hair;
Context
2“Sọ fún àwọn ọmọ Israẹli kí wọn mú ọrẹ wá fún mi, ìwọ yóò gba ọrẹ náà fún mi ni ọwọ́ ọkùnrin kọ̀ọ̀kan ti ọkàn rẹ bá fẹ́ láti fi fún mi. 3“Wọ̀nyí ni ọrẹ ti ìwọ yóò gbà ni ọwọ́ wọn:
“wúrà, fàdákà àti idẹ; 4aṣọ aláró, elése àlùkò, òdòdó, ọ̀gbọ̀;
irun ewúrẹ́. 5Awọ àgbò tí a rẹ ní pupa àti awọ ewúrẹ́ igbó;
igi kasia; 6Òróró olifi fún iná títàn;
òróró olóòórùn dídùn fún ìtasórí àti fún tùràrí olóòórùn dídùn;
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.