Eksodu 25:6
Exodus 25:6 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Òróró olifi fún iná títàn; òróró olóòórùn dídùn fún ìtasórí àti fún tùràrí olóòórùn dídùn;
Exodus 25:6 in English
Exodus 25:6 · Berean Standard Bible
olive oil for the light; spices for the anointing oil and for the fragrant incense;
Context
4aṣọ aláró, elése àlùkò, òdòdó, ọ̀gbọ̀;
irun ewúrẹ́. 5Awọ àgbò tí a rẹ ní pupa àti awọ ewúrẹ́ igbó;
igi kasia; 6Òróró olifi fún iná títàn;
òróró olóòórùn dídùn fún ìtasórí àti fún tùràrí olóòórùn dídùn; 7àti òkúta óníkìsì àti òkúta olówó iyebíye ti a fi ṣe ọ̀ṣọ́ sí ara ẹ̀wù efodu àti ẹ̀wù ìgbàyà. 8“Nígbà náà ni ìwọ yóò jẹ́ kí wọn kọ́ ibi mímọ́ fún mi. Èmi yóò sì máa gbé ní àárín wọn.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.