Native Bible

Exodus 25:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Olúwa sì wí fún Mose pé,

Exodus 25:1 in English

Exodus 25:1 · Berean Standard Bible

Then the LORD said to Moses,

Context

1Olúwa sì wí fún Mose pé, 2“Sọ fún àwọn ọmọ Israẹli kí wọn mú ọrẹ wá fún mi, ìwọ yóò gba ọrẹ náà fún mi ni ọwọ́ ọkùnrin kọ̀ọ̀kan ti ọkàn rẹ bá fẹ́ láti fi fún mi. 3“Wọ̀nyí ni ọrẹ ti ìwọ yóò gbà ni ọwọ́ wọn: “wúrà, fàdákà àti idẹ;

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.