Eksodu 22:19
Exodus 22:19 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
“Ẹnikẹ́ni ti ó bá bá ẹranko lòpọ̀ ní a ó pa.
Exodus 22:19 in English
Exodus 22:19 · Berean Standard Bible
Whoever lies with an animal must surely be put to death.
Context
17Bí baba ọmọbìnrin náà bá kọ̀ jálẹ̀ láti fi fún un ní aya, ó ni láti san owó tó tó owó orí rẹ̀ fún fífẹ́ ẹ ní wúńdíá. 18“Má ṣe jẹ́ kí àjẹ́ kí ó wà láààyè. 19“Ẹnikẹ́ni ti ó bá bá ẹranko lòpọ̀ ní a ó pa. 20“Ẹnikẹ́ni ti ó bá rú ẹbọ sí òrìṣà yàtọ̀ sí Olúwa nìkan, ni a ó yà sọ́tọ̀ fún ìparun. 21“Ẹ má ṣe fi ìyà jẹ àlejò tàbí ni wọ́n lára, nítorí ìwọ pẹ̀lú ti jẹ́ àjèjì ni ilẹ̀ Ejibiti rí.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.