Native Bible

Exodus 22:21 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

“Ẹ má ṣe fi ìyà jẹ àlejò tàbí ni wọ́n lára, nítorí ìwọ pẹ̀lú ti jẹ́ àjèjì ni ilẹ̀ Ejibiti rí.

Exodus 22:21 in English

Exodus 22:21 · Berean Standard Bible

You must not exploit or oppress a foreign resident, for you yourselves were foreigners in the land of Egypt.

Context

19“Ẹnikẹ́ni ti ó bá bá ẹranko lòpọ̀ ní a ó pa. 20“Ẹnikẹ́ni ti ó bá rú ẹbọ sí òrìṣà yàtọ̀ sí Olúwa nìkan, ni a ó yà sọ́tọ̀ fún ìparun. 21“Ẹ má ṣe fi ìyà jẹ àlejò tàbí ni wọ́n lára, nítorí ìwọ pẹ̀lú ti jẹ́ àjèjì ni ilẹ̀ Ejibiti rí. 22“Má ṣe yan opó tàbí ọmọ òrukàn jẹ. 23Bí ìwọ bá ṣe bẹ́ẹ̀, bí wọn bá ké pè mi. Èmi yóò sì gbọ́ ohùn igbe wọn.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.