Native Bible

Exodus 22:20 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

“Ẹnikẹ́ni ti ó bá rú ẹbọ sí òrìṣà yàtọ̀ sí Olúwa nìkan, ni a ó yà sọ́tọ̀ fún ìparun.

Exodus 22:20 in English

Exodus 22:20 · Berean Standard Bible

If anyone sacrifices to any god other than the LORD alone, he must be set apart for destruction.*

Context

18“Má ṣe jẹ́ kí àjẹ́ kí ó wà láààyè. 19“Ẹnikẹ́ni ti ó bá bá ẹranko lòpọ̀ ní a ó pa. 20“Ẹnikẹ́ni ti ó bá rú ẹbọ sí òrìṣà yàtọ̀ sí Olúwa nìkan, ni a ó yà sọ́tọ̀ fún ìparun. 21“Ẹ má ṣe fi ìyà jẹ àlejò tàbí ni wọ́n lára, nítorí ìwọ pẹ̀lú ti jẹ́ àjèjì ni ilẹ̀ Ejibiti rí. 22“Má ṣe yan opó tàbí ọmọ òrukàn jẹ.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.