Eksodu 21:1
Exodus 21:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
“Wọ̀nyí ni àwọn òfin tí ìwọ yóò gbé sí iwájú wọn.
Exodus 21:1 in English
Exodus 21:1 · Berean Standard Bible
“These are the ordinances that you are to set before them:
Context
1“Wọ̀nyí ni àwọn òfin tí ìwọ yóò gbé sí iwájú wọn. 2“Bí ìwọ bá yá ọkùnrin Heberu ní ìwẹ̀fà, òun yóò sìn ọ́ fún ọdún mẹ́fà. Ṣùgbọ́n ní ọdún keje, òun yóò lọ ni òmìnira láìsan ohunkóhun padà. 3Bí ó bá wá ní òun nìkan, òun nìkan náà ni yóò padà lọ ní òmìnira; ṣùgbọ́n tí ó bá mú ìyàwó wá, ó ní láti mú ìyàwó rẹ̀ padà lọ.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.