Native Bible

Exodus 20:2 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

“Èmi ni Olúwa Ọlọ́run yín, tí ó mú un yín jáde láti ilẹ̀ Ejibiti, láti oko ẹrú jáde wá.

Exodus 20:2 in English

Exodus 20:2 · Berean Standard Bible

“I am the LORD your God, who brought you out of the land of Egypt, out of the house of slavery.

Context

1Ọlọ́run sì sọ gbogbo ọ̀rọ̀ yìí pé, 2“Èmi ni Olúwa Ọlọ́run yín, tí ó mú un yín jáde láti ilẹ̀ Ejibiti, láti oko ẹrú jáde wá. 3“Ìwọ kò gbọdọ̀ ní ọlọ́run mìíràn pẹ̀lú mi. 4Ìwọ kò gbọdọ̀ ṣe ère fún ara yín, tàbí àwòrán ohun kan tí ń bẹ ní òkè ọ̀run, tàbí ti ohun kan tí ń bẹ ní ìsàlẹ̀ ilẹ̀, tàbí ti ohun kan tí ń bẹ nínú omi ní ìsàlẹ̀ ilẹ̀.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.