Native Bible

Exodus 20:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ọlọ́run sì sọ gbogbo ọ̀rọ̀ yìí pé,

Exodus 20:1 in English

Exodus 20:1 · Berean Standard Bible

And God spoke all these words:

Context

1Ọlọ́run sì sọ gbogbo ọ̀rọ̀ yìí pé, 2“Èmi ni Olúwa Ọlọ́run yín, tí ó mú un yín jáde láti ilẹ̀ Ejibiti, láti oko ẹrú jáde wá. 3“Ìwọ kò gbọdọ̀ ní ọlọ́run mìíràn pẹ̀lú mi.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.