Oniwaasu 1:3
Ecclesiastes 1:3 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Kí ni ènìyàn rí jẹ ní èrè lórí gbogbo iṣẹ́ rẹ̀, lórí èyí tí ó ń ṣe wàhálà sí lábẹ́ oòrùn?
Ecclesiastes 1:3 in English
Ecclesiastes 1:3 · Berean Standard Bible
What does a man gain from all his labor, at which he toils under the sun?
Context
1Ọ̀rọ̀ Oniwaasu, ọmọ Dafidi, ọba Jerusalẹmu: 2“Asán inú asán!”
Oníwàásù náà wí pé,
“Asán inú asán!
Gbogbo rẹ̀ asán ni.” 3Kí ni ènìyàn rí jẹ ní èrè lórí gbogbo iṣẹ́ rẹ̀,
lórí èyí tí ó ń ṣe wàhálà sí lábẹ́ oòrùn? 4Bí ìran kan ti wá ni ìran mìíràn ń kọjá lọ,
síbẹ̀ ayé dúró títí láé. 5Oòrùn ń ràn, oòrùn sì ń wọ̀,
ó sì sáré padà sí ibi tí ó ti yọ.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.