Native Bible

Deuteronomy 5:2 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Olúwa Ọlọ́run wa bá wa dá májẹ̀mú ní Horebu.

Deuteronomy 5:2 in English

Deuteronomy 5:2 · Berean Standard Bible

The LORD our God made a covenant with us at Horeb.*

Context

1Mose sì pe gbogbo Israẹli jọ, ó sì wí pé, Gbọ́ ìwọ Israẹli, gbọ́ ìlànà àti òfin tí mo mú wá sí etí ìgbọ́ ọ yín lónìí. Ẹ kọ wọ́n, kí ẹ sì ri dájú pé ẹ̀ ń ṣe wọ́n. 2Olúwa Ọlọ́run wa bá wa dá májẹ̀mú ní Horebu. 3Kì í ṣe àwọn baba wa ni Olúwa bá dá májẹ̀mú yìí bí kò ṣe àwa, àní pẹ̀lú gbogbo àwa tí a wà láààyè níbí lónìí. 4Olúwa bá a yín sọ̀rọ̀ lójúkojú láàrín iná lórí òkè.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.