Native Bible

Deuteronomy 3:29 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Báyìí ni a dúró ní àfonífojì ní ẹ̀bá Beti-Peori.

Deuteronomy 3:29 in English

Deuteronomy 3:29 · Berean Standard Bible

So we stayed in the valley opposite Beth-peor.

Context

27Gòkè lọ sí orí òkè Pisga, sì wò yíká ìwọ̀-oòrùn, ìlà-oòrùn, àríwá àti gúúsù. Fi ojú ara rẹ wo ilẹ̀ náà níwọ̀n bí ìwọ kò tí ní kọjá Jordani yìí. 28Ṣùgbọ́n yan Joṣua, kí o sì gbà á níyànjú, mú un lọ́kàn le, torí pé òun ni yóò síwájú àwọn ènìyàn wọ̀nyí kọjá, yóò sì jẹ́ kí wọn jogún ilẹ̀ náà tí ìwọ yóò rí.” 29Báyìí ni a dúró ní àfonífojì ní ẹ̀bá Beti-Peori.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.