Native Bible

Deuteronomy 28:18 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ègún ni fún ọmọ inú rẹ, àti èso ilẹ̀ rẹ, ìbísí màlúù rẹ àti ọmọ àgùntàn rẹ.

Deuteronomy 28:18 in English

Deuteronomy 28:18 · Berean Standard Bible

The fruit of your womb will be cursed, as well as the produce of your land, the calves of your herds, and the lambs of your flocks.

Context

16Ègún ni fún ọ ní ìlú, ègún ni fún ọ ní oko. 17Ègún ni fún agbọ̀n rẹ àti ọpọ́n ìpo-fúláwà rẹ. 18Ègún ni fún ọmọ inú rẹ, àti èso ilẹ̀ rẹ, ìbísí màlúù rẹ àti ọmọ àgùntàn rẹ. 19Ègún ni fún ọ nígbà tí o bá wọlé ègún sì ni fún ọ nígbà tí ìwọ bá jáde. 20Olúwa yóò rán ègún sórí rẹ, rúdurùdu àti ìfibú nínú gbogbo ohun tí o bá dáwọ́ rẹ lé, títí ìwọ yóò fi parun àti wá sí ìparun lójijì nítorí búburú tí o ti ṣe ní kíkọ̀ mi sílẹ̀.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.