Native Bible

Deuteronomy 14:11 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ẹ lè jẹ ẹyẹ tí ó bá mọ́.

Deuteronomy 14:11 in English

Context

9Nínú gbogbo ẹ̀dá alààyè tí ń gbé inú omi, ẹ lè jẹ èyíkéyìí tí ó ní lẹbẹ àti ìpẹ́. 10Ṣùgbọ́n èyíkéyìí tí kò bá ní lẹbẹ àti ìpẹ́, ẹ má ṣe jẹ ẹ́, nítorí pé àìmọ́ ni wọ́n jẹ́ fún yín. 11Ẹ lè jẹ ẹyẹ tí ó bá mọ́. 12Ṣùgbọ́n ìwọ̀nyí ní ẹ kò gbọdọ̀ jẹ: idì, igún, àkàlà, 13onírúurú àṣá àti àṣá alátagbà,

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.