Native Bible

Deuteronomy 14:12 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ṣùgbọ́n ìwọ̀nyí ní ẹ kò gbọdọ̀ jẹ: idì, igún, àkàlà,

Deuteronomy 14:12 in English

Deuteronomy 14:12 · Berean Standard Bible

but these you may not eat: the eagle, the bearded vulture, the black vulture,

Context

10Ṣùgbọ́n èyíkéyìí tí kò bá ní lẹbẹ àti ìpẹ́, ẹ má ṣe jẹ ẹ́, nítorí pé àìmọ́ ni wọ́n jẹ́ fún yín. 11Ẹ lè jẹ ẹyẹ tí ó bá mọ́. 12Ṣùgbọ́n ìwọ̀nyí ní ẹ kò gbọdọ̀ jẹ: idì, igún, àkàlà, 13onírúurú àṣá àti àṣá alátagbà, 14onírúurú ẹyẹ ìwò,

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.