Native Bible

Acts 7:48 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

“Ṣùgbọ́n Ọ̀gá-ògo kì í gbé ilé ti a fi ọwọ́ kọ́, gẹ́gẹ́ bí wòlíì ti wí pé:

Acts 7:48 in English

Acts 7:48 · Berean Standard Bible

However, the Most High does not dwell in houses made by human hands. As the prophet says:

Context

46Ẹni tí ó rí ojúrere níwájú Ọlọ́run, tí ó sì tọrọ láti rí ibùgbé fún Ọlọ́run Jakọbu. 47Ṣùgbọ́n Solomoni ni ó kọ́ ilé fún un. 48“Ṣùgbọ́n Ọ̀gá-ògo kì í gbé ilé ti a fi ọwọ́ kọ́, gẹ́gẹ́ bí wòlíì ti wí pé: 49“ ‘Ọ̀run ni ìtẹ́ mi, ayé ni àpótí ìtìsẹ̀ mi. Irú ilé kín ní ẹ̀yin yóò kọ́ fún mi? ni Olúwa wí. Tàbí níbo ni yóò jẹ́ ibi ìsinmi mi? 50Ọwọ́ mi kò ha ṣe gbogbo nǹkan wọ̀nyí.’

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.