2 Samuẹli 5:15
2 Samuel 5:15 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àti Ibhari, àti Eliṣua, àti Nefegi, àti Jafia.
2 Samuel 5:15 in English
2 Samuel 5:15 · Berean Standard Bible
Ibhar, Elishua, Nepheg, Japhia,
Context
13Dafidi sì tún mú àwọn àlè àti aya sí i láti Jerusalẹmu wá, lẹ́yìn ìgbà tí ó ti Hebroni bọ̀, wọ́n sì bí ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin fún Dafidi. 14Èyí sì ni orúkọ àwọn tí a bí fún un ní Jerusalẹmu; Ṣammua, Ṣobabu, Natani àti Solomoni. 15Àti Ibhari, àti Eliṣua, àti Nefegi, àti Jafia. 16Àti Eliṣama, àti Eliada, àti Elifeleti. 17Ṣùgbọ́n nígbà tí àwọn Filistini gbọ́ pé, wọ́n ti fi Dafidi jẹ ọba lórí Israẹli, gbogbo àwọn Filistini sì gòkè wá láti wá Dafidi; Dafidi sì gbọ́, ó sì sọ̀kalẹ̀ lọ sí ìlú olódi.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.