2 Samuẹli 22:28
2 Samuel 22:28 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àwọn ènìyàn tí ó wà nínú ìyà ni ìwọ ó sì gbàlà; ṣùgbọ́n ojú rẹ wà lára àwọn agbéraga, láti rẹ̀ wọ́n sílẹ̀.
2 Samuel 22:28 in English
2 Samuel 22:28 · Berean Standard Bible
You save an afflicted people, but Your eyes are on the haughty to bring them down.
Context
26“Fún aláàánú ni ìwọ ó fi ara rẹ̀ hàn ni aláàánú,
àti fún ẹni ìdúró ṣinṣin ní òdodo ni ìwọ ó fi ara rẹ hàn ní ìdúró ṣinṣin ní òdodo. 27Fún onínú funfun ni ìwọ fi ara rẹ hàn ní funfun;
àti fún ẹni wíwọ́ ni ìwọ ó fi ara rẹ hàn ní wíwọ́. 28Àwọn ènìyàn tí ó wà nínú ìyà ni ìwọ ó sì gbàlà;
ṣùgbọ́n ojú rẹ wà lára àwọn agbéraga, láti rẹ̀ wọ́n sílẹ̀. 29Nítorí ìwọ ni ìmọ́lẹ̀ mi, Olúwa;
Olúwa yóò sì sọ òkùnkùn mi di ìmọ́lẹ̀. 30Bẹ́ẹ̀ ni nítorí nípa rẹ̀ ni èmi ti la àárín ogun kọjá;
nípa Ọlọ́run mi èmi ti fo odi kan.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.