2 Samuẹli 1:18
2 Samuel 1:18 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ó sì pàṣẹ pé kí a kọ́ àwọn ọkùnrin Juda ní orin arò yìí tí ó jẹ́ ti ọrun (a kọ ọ́ sí inú ìwé Jaṣari):
2 Samuel 1:18 in English
2 Samuel 1:18 · Berean Standard Bible
and he ordered that the sons of Judah be taught the Song of the Bow.* It is written in the Book of Jashar:*
Context
16Nítorí Dafidi wí fún un pé, “Ẹ̀jẹ̀ rẹ yóò wà lórí ara rẹ, nítorí ẹnu ara rẹ ni o fi sọ pé, ‘Mo pa ẹni àmì òróró Olúwa.’ ” 17Dafidi sì fi orin ọ̀fọ̀ yìí ṣọ̀fọ̀ lórí Saulu àti lórí Jonatani ọmọ rẹ̀, 18Ó sì pàṣẹ pé kí a kọ́ àwọn ọkùnrin Juda ní orin arò yìí tí ó jẹ́ ti ọrun (a kọ ọ́ sí inú ìwé Jaṣari): 19“Ògo rẹ, Israẹli ni a pa ní òkè gíga rẹ.
Wò bí àwọn alágbára ṣe ń ṣubú! 20“Ẹ má ṣe sọ ọ́ ní Gati,
ẹ má ṣe kéde rẹ̀ ní òpópónà Aṣkeloni,
kí àwọn ọmọbìnrin Filistini má bá à yọ̀,
kí àwọn ọmọbìnrin aláìkọlà má ba à dunnú.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.