Native Bible

2 Chronicles 4:15 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

agbada ńlá kan àti màlúù méjìlá lábẹ́ rẹ̀;

2 Chronicles 4:15 in English

2 Chronicles 4:15 · Berean Standard Bible

the Sea; the twelve oxen underneath the Sea;

Context

13irinwó (400) pomegiranate fún iṣẹ́ ẹ̀wọ̀n méjì náà, ẹsẹ̀ méjì pomegiranate ni fún iṣẹ́ ẹ̀wọ̀n kan, láti bo ọpọ́n rìbìtì méjì náà tí ó wà lórí àwọn òpó náà; 14ó sì ṣe àgbéró ó sì ṣe agbada sí orí wọn; 15agbada ńlá kan àti màlúù méjìlá lábẹ́ rẹ̀; 16àwọn ìkòkò àti ọ̀kọ̀ àti àmúga ẹran àti gbogbo ohun èlò tí ó fi ara pẹ́ ẹ. Gbogbo ohun èlò ti Huramu-Abi fi idẹ dídán ṣe fún Solomoni ọba, fún ilé Olúwa jẹ́ idẹ dídán. 17Ọba dà wọ́n ní ilẹ̀ amọ̀ ní pẹ̀tẹ́lẹ̀ Jordani ní àárín méjì Sukkoti àti Sereda.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.