Native Bible

2 Chronicles 4:14 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

ó sì ṣe àgbéró ó sì ṣe agbada sí orí wọn;

2 Chronicles 4:14 in English

2 Chronicles 4:14 · Berean Standard Bible

the stands; the basins on the stands;

Context

12Àwọn ọ̀wọ́n méjì; ọpọ́n méjì ìparí tí ó wà lókè àwọn ọ̀wọ́n iṣẹ́; àwọn méjì ní láti bo ọpọ́n méjì ìparí tí ń bẹ lókè àwọn ọ̀wọ́n; 13irinwó (400) pomegiranate fún iṣẹ́ ẹ̀wọ̀n méjì náà, ẹsẹ̀ méjì pomegiranate ni fún iṣẹ́ ẹ̀wọ̀n kan, láti bo ọpọ́n rìbìtì méjì náà tí ó wà lórí àwọn òpó náà; 14ó sì ṣe àgbéró ó sì ṣe agbada sí orí wọn; 15agbada ńlá kan àti màlúù méjìlá lábẹ́ rẹ̀; 16àwọn ìkòkò àti ọ̀kọ̀ àti àmúga ẹran àti gbogbo ohun èlò tí ó fi ara pẹ́ ẹ. Gbogbo ohun èlò ti Huramu-Abi fi idẹ dídán ṣe fún Solomoni ọba, fún ilé Olúwa jẹ́ idẹ dídán.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.