1 Peteru 5:14
1 Peter 5:14 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ẹ fi ìfẹ́nukonu ìfẹ́ kí ara, yín. Àlàáfíà fún gbogbo yín tí ẹ wà nínú Kristi.
1 Peter 5:14 in English
1 Peter 5:14 · Berean Standard Bible
Greet one another with a kiss of love. Peace to all of you who are in Christ.*
Context
12Nítorí Sila, arákùnrin wa olóòtítọ́ gẹ́gẹ́ bí mo ti kà á sí, ni mo kọ̀wé kúkúrú sí i yín, tí mo ń gbà yín níyànjú, tí mo sì ń jẹ́rìí pé, èyí ni òtítọ́ oore-ọ̀fẹ́ Ọlọ́run: ẹ dúró ṣinṣin nínú rẹ̀. 13Ìjọ tí ń bẹ ní Babeli, tí a yàn, pẹ̀lú kí yín, bẹ́ẹ̀ sì ni Marku ọmọ mi pẹ̀lú. 14Ẹ fi ìfẹ́nukonu ìfẹ́ kí ara, yín.
Àlàáfíà fún gbogbo yín tí ẹ wà nínú Kristi.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.