1 Peteru 5:13
1 Peter 5:13 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ìjọ tí ń bẹ ní Babeli, tí a yàn, pẹ̀lú kí yín, bẹ́ẹ̀ sì ni Marku ọmọ mi pẹ̀lú.
1 Peter 5:13 in English
1 Peter 5:13 · Berean Standard Bible
The church in Babylon,* chosen together with you, sends you greetings, as does my son Mark.
Context
11Tìrẹ ni ògo àti agbára títí láé. Àmín. 12Nítorí Sila, arákùnrin wa olóòtítọ́ gẹ́gẹ́ bí mo ti kà á sí, ni mo kọ̀wé kúkúrú sí i yín, tí mo ń gbà yín níyànjú, tí mo sì ń jẹ́rìí pé, èyí ni òtítọ́ oore-ọ̀fẹ́ Ọlọ́run: ẹ dúró ṣinṣin nínú rẹ̀. 13Ìjọ tí ń bẹ ní Babeli, tí a yàn, pẹ̀lú kí yín, bẹ́ẹ̀ sì ni Marku ọmọ mi pẹ̀lú. 14Ẹ fi ìfẹ́nukonu ìfẹ́ kí ara, yín.
Àlàáfíà fún gbogbo yín tí ẹ wà nínú Kristi.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.