1 Ọba 14:1
1 Kings 14:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ní àkókò náà Abijah ọmọ Jeroboamu sì ṣàìsàn,
1 Kings 14:1 in English
1 Kings 14:1 · Berean Standard Bible
At that time Abijah son of Jeroboam became ill,
Context
1Ní àkókò náà Abijah ọmọ Jeroboamu sì ṣàìsàn, 2Jeroboamu sì wí fún aya rẹ̀ pé, “Lọ, sì pa ara rẹ dà, kí wọn kí ó má ba à mọ̀ ọ́n ní aya Jeroboamu. Nígbà náà ni kí o lọ sí Ṣilo. Ahijah wòlíì wà níbẹ̀; ẹni tí ó sọ fún mi pé, èmi yóò jẹ ọba lórí àwọn ènìyàn yìí. 3Mú ìṣù àkàrà mẹ́wàá pẹ̀lú rẹ̀, àti àkàrà wẹ́wẹ́ àti ìgò oyin, kí o sì lọ sí ọ̀dọ̀ rẹ̀. Òun yóò sì sọ fún ọ ohun tí yóò ṣẹlẹ̀ sí ọmọkùnrin náà.”
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.