Native Bible

1 Chronicles 8:6 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Wọ̀nyí ni àwọn ìran ọmọ Ehudu, tí wọ́n jẹ́ olórí àwọn ìdílé tí ó ń gbé ní Geba tí a sì lé kúrò lọ sí Manahati:

1 Chronicles 8:6 in English

1 Chronicles 8:6 · Berean Standard Bible

These were the descendants of Ehud who were the heads of the families living in Geba and were exiled to Manahath:

Context

4Abiṣua, Naamani, Ahoa, 5Gera, Ṣefufani àti Huramu. 6Wọ̀nyí ni àwọn ìran ọmọ Ehudu, tí wọ́n jẹ́ olórí àwọn ìdílé tí ó ń gbé ní Geba tí a sì lé kúrò lọ sí Manahati: 7Naamani Ahijah àti Gera, tí ó lé wọn kúrò ní ìlú, àti tí ó sì jẹ́ baba Ussa àti Ahihudu. 8A bí àwọn ọmọkùnrin fún Ṣaharaimu ní Moabu lẹ́yìn tí ó ti kọ àwọn ìyàwó rẹ̀ sílẹ̀, Huṣimu àti Baara.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.