Native Bible

1 Chronicles 8:5 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Gera, Ṣefufani àti Huramu.

1 Chronicles 8:5 in English

1 Chronicles 8:5 · Berean Standard Bible

Gera, Shephuphan, and Huram.

Context

3Àwọn ọmọ Bela ni, Adari, Gera, Abihudi, 4Abiṣua, Naamani, Ahoa, 5Gera, Ṣefufani àti Huramu. 6Wọ̀nyí ni àwọn ìran ọmọ Ehudu, tí wọ́n jẹ́ olórí àwọn ìdílé tí ó ń gbé ní Geba tí a sì lé kúrò lọ sí Manahati: 7Naamani Ahijah àti Gera, tí ó lé wọn kúrò ní ìlú, àti tí ó sì jẹ́ baba Ussa àti Ahihudu.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.