Native Bible

1 Chronicles 7:39 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àwọn ọmọ Ulla: Arah, Hannieli àti Resia.

1 Chronicles 7:39 in English

1 Chronicles 7:39 · Berean Standard Bible

The sons of Ulla: Arah, Hanniel, and Rizia.

Context

37Beseri, Hodi, Ṣamma, Ṣilisa, Itrani àti Bera. 38Àwọn ọmọ Jeteri: Jefunne, Pisifa àti Ara. 39Àwọn ọmọ Ulla: Arah, Hannieli àti Resia. 40Gbogbo wọ̀nyí jẹ́ ìran ọmọ Aṣeri—olórí ìdílé, àṣàyàn ọkùnrin, alágbára jagunjagun àti olórí nínú àwọn ìjòyè. Iye àwọn tí a kà yẹ fún ogun, gẹ́gẹ́ bí à ti ṣe kọ ọ́ lẹ́sẹẹsẹ nínú ìtàn ìdílé wọn jẹ́ ẹgbàá mẹ́tàlá (26,000) ọkùnrin.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.