1 Kronika 7:38
1 Chronicles 7:38 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àwọn ọmọ Jeteri: Jefunne, Pisifa àti Ara.
1 Chronicles 7:38 in English
1 Chronicles 7:38 · Berean Standard Bible
The sons of Jether: Jephunneh, Pispa, and Ara.
Context
36Àwọn ọmọ Sofahi:
Sua, Haniferi, Ṣuali, Beri, Imra. 37Beseri, Hodi, Ṣamma, Ṣilisa, Itrani àti Bera. 38Àwọn ọmọ Jeteri:
Jefunne, Pisifa àti Ara. 39Àwọn ọmọ Ulla:
Arah, Hannieli àti Resia. 40Gbogbo wọ̀nyí jẹ́ ìran ọmọ Aṣeri—olórí ìdílé, àṣàyàn ọkùnrin, alágbára jagunjagun àti olórí nínú àwọn ìjòyè. Iye àwọn tí a kà yẹ fún ogun, gẹ́gẹ́ bí à ti ṣe kọ ọ́ lẹ́sẹẹsẹ nínú ìtàn ìdílé wọn jẹ́ ẹgbàá mẹ́tàlá (26,000) ọkùnrin.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.