1 Kronika 7:34
1 Chronicles 7:34 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àwọn ọmọ Ṣomeri: Ahi, Roga, Jahuba àti Aramu.
1 Chronicles 7:34 in English
1 Chronicles 7:34 · Berean Standard Bible
The sons of Shemer: Ahi, Rohgah,* Hubbah, and Aram.
Context
32Heberi jẹ́ baba Jafileti, Ṣomeri àti Hotami àti ti arábìnrin wọn Ṣua. 33Àwọn ọmọ Jafileti:
Pasaki, Bimhali àti Asifati.
Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Jafileti. 34Àwọn ọmọ Ṣomeri:
Ahi, Roga, Jahuba àti Aramu. 35Àwọn ọmọ arákùnrin rẹ̀ Helemu
Sofahi, Imina, Ṣeleṣi àti Amali. 36Àwọn ọmọ Sofahi:
Sua, Haniferi, Ṣuali, Beri, Imra.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.