1 Kronika 7:33
1 Chronicles 7:33 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àwọn ọmọ Jafileti: Pasaki, Bimhali àti Asifati. Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Jafileti.
1 Chronicles 7:33 in English
1 Chronicles 7:33 · Berean Standard Bible
The sons of Japhlet: Pasach, Bimhal, and Ashvath. These were Japhlet’s sons.
Context
31Àwọn ọmọ Beriah:
Heberi àti Malkieli, tí ó jẹ́ baba Barsafiti. 32Heberi jẹ́ baba Jafileti, Ṣomeri àti Hotami àti ti arábìnrin wọn Ṣua. 33Àwọn ọmọ Jafileti:
Pasaki, Bimhali àti Asifati.
Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Jafileti. 34Àwọn ọmọ Ṣomeri:
Ahi, Roga, Jahuba àti Aramu. 35Àwọn ọmọ arákùnrin rẹ̀ Helemu
Sofahi, Imina, Ṣeleṣi àti Amali.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.