Native Bible

1 Chronicles 6:47 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

ọmọ Mahili, ọmọ Muṣi, ọmọ Merari, ọmọ Lefi.

1 Chronicles 6:47 in English

1 Chronicles 6:47 · Berean Standard Bible

the son of Mahli, the son of Mushi, the son of Merari, the son of Levi.

Context

45ọmọ Haṣabiah, ọmọ Amasiah, ọmọ Hilkiah, 46ọmọ Amisi, ọmọ Bani, ọmọ Ṣemeri, 47ọmọ Mahili, ọmọ Muṣi, ọmọ Merari, ọmọ Lefi. 48Àwọn Lefi ẹgbẹ́ wọn ni wọn yan àwọn iṣẹ́ yòókù ti àgọ́ fún, èyí tí í ṣe ilé Ọlọ́run. 49Ṣùgbọ́n Aaroni àti àwọn ìran ọmọ rẹ̀ jẹ́ àwọn tí ó gbé ọrẹ kalẹ̀ lórí pẹpẹ ẹbọ sísun àti lórí pẹpẹ tùràrí ní ìbátan pẹ̀lú gbogbo ohun tí a ṣe ní Ibi Mímọ́ Jùlọ. Ṣíṣe ètùtù fún Israẹli, ní ìbámu pẹ̀lú gbogbo ohun tí Mose ìránṣẹ́ Ọlọ́run ti pàṣẹ.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.