Native Bible

1 Chronicles 6:46 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

ọmọ Amisi, ọmọ Bani, ọmọ Ṣemeri,

1 Chronicles 6:46 in English

1 Chronicles 6:46 · Berean Standard Bible

the son of Amzi, the son of Bani, the son of Shemer,

Context

44láti ìbákẹ́gbẹ́ wọn, àwọn ará Merari wà ní ọwọ́ òsì rẹ̀: Etani ọmọ Kiṣi, ọmọ Abdi, ọmọ Malluki, 45ọmọ Haṣabiah, ọmọ Amasiah, ọmọ Hilkiah, 46ọmọ Amisi, ọmọ Bani, ọmọ Ṣemeri, 47ọmọ Mahili, ọmọ Muṣi, ọmọ Merari, ọmọ Lefi. 48Àwọn Lefi ẹgbẹ́ wọn ni wọn yan àwọn iṣẹ́ yòókù ti àgọ́ fún, èyí tí í ṣe ilé Ọlọ́run.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.