1 Kronika 6:34
1 Chronicles 6:34 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
ọmọ Elkana, ọmọ Jerohamu, ọmọ Elieli, ọmọ Toha,
1 Chronicles 6:34 in English
1 Chronicles 6:34 · Berean Standard Bible
the son of Elkanah, the son of Jeroham, the son of Eliel,* the son of Toah,
Context
32Wọ́n jíṣẹ́ pẹ̀lú orin níwájú àgọ́ ìpàdé títí tí Solomoni fi kọ́ ilé Olúwa ní Jerusalẹmu. Wọ́n ṣe iṣẹ́ ìsìn wọn ní ìbámu pẹ̀lú ìlànà tí a fi lélẹ̀ fún wọn. 33Wọ̀nyí ni àwọn ọkùnrin tí ó sìn pẹ̀lú ọmọ wọn.
Láti ọ̀dọ̀ àwọn ará Kohati:
Hemani olùkọrin,
ọmọ Joẹli, ọmọ Samuẹli, 34ọmọ Elkana, ọmọ Jerohamu,
ọmọ Elieli, ọmọ Toha, 35ọmọ Sufu, ọmọ Elkana,
ọmọ Mahati, ọmọ Amasai, 36ọmọ Elkana, ọmọ Joẹli,
ọmọ Asariah, ọmọ Sefaniah,
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.