Native Bible

1 Chronicles 3:18 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Malkiramu, Pedaiah, Ṣenasari, Jekamiah, Hoṣama àti Nedabiah.

1 Chronicles 3:18 in English

1 Chronicles 3:18 · Berean Standard Bible

Malchiram, Pedaiah, Shenazzar, Jekamiah, Hoshama, and Nedabiah.

Context

16Àwọn ìran ọmọ Jehoiakimu: Jekoniah ọmọ rẹ̀, àti Sedekiah. 17Àwọn ọmọ Jekoniah tí a mú ní ìgbèkùn: Ṣealitieli ọmọ rẹ̀ ọkùnrin, 18Malkiramu, Pedaiah, Ṣenasari, Jekamiah, Hoṣama àti Nedabiah. 19Àwọn ọmọ Pedaiah: Serubbabeli àti Ṣimei. Àwọn ọmọ Serubbabeli: Meṣullamu àti Hananiah. Ṣelomiti ni arábìnrin wọn. 20Àwọn márùn-ún mìíràn sì tún wà: Haṣuba, Oheli, Berekiah, Hasadiah àti Jusabhesedi.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.