Native Bible

1 Chronicles 3:20 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àwọn márùn-ún mìíràn sì tún wà: Haṣuba, Oheli, Berekiah, Hasadiah àti Jusabhesedi.

1 Chronicles 3:20 in English

1 Chronicles 3:20 · Berean Standard Bible

and five others: Hashubah, Ohel, Berechiah, Hasadiah, and Jushab-hesed.

Context

18Malkiramu, Pedaiah, Ṣenasari, Jekamiah, Hoṣama àti Nedabiah. 19Àwọn ọmọ Pedaiah: Serubbabeli àti Ṣimei. Àwọn ọmọ Serubbabeli: Meṣullamu àti Hananiah. Ṣelomiti ni arábìnrin wọn. 20Àwọn márùn-ún mìíràn sì tún wà: Haṣuba, Oheli, Berekiah, Hasadiah àti Jusabhesedi. 21Àwọn ọmọ Hananiah: Pelatiah àti Jeṣaiah, àti àwọn ọmọ Refaiah, ti Arnani, ti Obadiah àti ti Ṣekaniah. 22Àwọn ọmọ Ṣekaniah: Ṣemaiah àti àwọn ọmọ rẹ̀: Hattusi, Igali, Bariah, Neariah àti Ṣafati, mẹ́fà ni gbogbo wọn.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.