1 Kronika 27:17
1 Chronicles 27:17 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
lórí Lefi: Haṣabiah ọmọ Kemueli; lórí Aaroni: Sadoku;
1 Chronicles 27:17 in English
1 Chronicles 27:17 · Berean Standard Bible
over Levi was Hashabiah son of Kemuel; over Aaron was Zadok;
Context
15Èkejìlá fún oṣù kejìlá jẹ́ Heldai ará Netofa láti ìdílé Otnieli. Ẹgbàá méjìlá (24,000) ọkùnrin ni ó wà ní ìpín tirẹ̀. 16Àwọn ìjòyè lórí àwọn ẹ̀yà tí Israẹli:
lórí àwọn ará Reubeni: Elieseri ọmọ Sikri;
lórí àwọn ọmọ Simeoni: Ṣefatia ọmọ Maaka; 17lórí Lefi: Haṣabiah ọmọ Kemueli;
lórí Aaroni: Sadoku; 18lórí Juda: Elihu arákùnrin Dafidi;
lórí Isakari: Omri ọmọ Mikaeli; 19lórí Sebuluni: Iṣmaiah ọmọ Obadiah;
lórí Naftali: Jerimoti ọmọ Asrieli;
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.