1 Kronika 27:15
1 Chronicles 27:15 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Èkejìlá fún oṣù kejìlá jẹ́ Heldai ará Netofa láti ìdílé Otnieli. Ẹgbàá méjìlá (24,000) ọkùnrin ni ó wà ní ìpín tirẹ̀.
1 Chronicles 27:15 in English
1 Chronicles 27:15 · Berean Standard Bible
The twelfth, for the twelfth month, was Heldai * the Netophathite, from the family of Othniel. There were 24,000 men in his division.
Context
13Ẹ̀kẹwàá fún oṣù kẹwàá jẹ́ Maharai ará Netofa, ará Sera ọkùnrin ẹgbàá méjìlá (24,000) ni ó wà ní ìpín rẹ̀. 14Ìkọkànlá fún oṣù kọkànlá jẹ́ Benaiah ará Piratoni ará Efraimu ọkùnrin ẹgbàá méjìlá (24,000) ni ó wà ní ìpín tirẹ̀. 15Èkejìlá fún oṣù kejìlá jẹ́ Heldai ará Netofa láti ìdílé Otnieli. Ẹgbàá méjìlá (24,000) ọkùnrin ni ó wà ní ìpín tirẹ̀. 16Àwọn ìjòyè lórí àwọn ẹ̀yà tí Israẹli:
lórí àwọn ará Reubeni: Elieseri ọmọ Sikri;
lórí àwọn ọmọ Simeoni: Ṣefatia ọmọ Maaka; 17lórí Lefi: Haṣabiah ọmọ Kemueli;
lórí Aaroni: Sadoku;
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.