Native Bible

1 Chronicles 2:51 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Salma baba Bẹtilẹhẹmu àti Harefu baba Beti-Gaderi.

1 Chronicles 2:51 in English

1 Chronicles 2:51 · Berean Standard Bible

Salma the father of Bethlehem, and Hareph the father of Beth-gader.

Context

49Ó sì bí Ṣaafu baba Madmana, Ṣefa baba Makbena àti baba Gibeah, ọmọbìnrin Kalebu sì ni Aksa. 50Àwọn wọ̀nyí ni ọmọ Kalebu. Àwọn ọmọ Huri, àkọ́bí Efrata: Ṣobali baba Kiriati-Jearimu. 51Salma baba Bẹtilẹhẹmu àti Harefu baba Beti-Gaderi. 52Àwọn ọmọ Ṣobali baba Kiriati-Jearimu ni: Haroe, ìdajì àwọn ará Manaheti. 53Àti ìdílé Kiriati-Jearimu: àti àwọn ara Itri, àti àwọn ará Puti, àti àwọn ará Ṣumati àti àwọn ará Miṣraiti: láti ọ̀dọ̀ wọn ni àwọn ọmọ ará Sorati àti àwọn ará Eṣtaoli ti wá.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.