1 Kronika 2:52
1 Chronicles 2:52 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àwọn ọmọ Ṣobali baba Kiriati-Jearimu ni: Haroe, ìdajì àwọn ará Manaheti.
1 Chronicles 2:52 in English
1 Chronicles 2:52 · Berean Standard Bible
These were the descendants of Shobal the father of Kiriath-jearim: Haroeh, half the Manahathites,
Context
50Àwọn wọ̀nyí ni ọmọ Kalebu.
Àwọn ọmọ Huri, àkọ́bí Efrata:
Ṣobali baba Kiriati-Jearimu. 51Salma baba Bẹtilẹhẹmu àti Harefu baba Beti-Gaderi. 52Àwọn ọmọ Ṣobali baba Kiriati-Jearimu ni:
Haroe, ìdajì àwọn ará Manaheti. 53Àti ìdílé Kiriati-Jearimu: àti àwọn ara Itri, àti àwọn ará Puti, àti àwọn ará Ṣumati àti àwọn ará Miṣraiti: láti ọ̀dọ̀ wọn ni àwọn ọmọ ará Sorati àti àwọn ará Eṣtaoli ti wá. 54Àwọn ọmọ Salma:
Bẹtilẹhẹmu, àti àwọn ará Netofa, Atrotu Beti-Joabu, ìdajì àwọn ará Manahati, àti ará Sori,
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.