1 Kronika 2:17
1 Chronicles 2:17 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Abigaili ni ìyá Amasa, ẹni tí baba rẹ̀ sì jẹ́ Jeteri ará Iṣmaeli.
1 Chronicles 2:17 in English
1 Chronicles 2:17 · Berean Standard Bible
Abigail was the mother of Amasa, whose father was Jether * the Ishmaelite.
Context
15ẹlẹ́ẹ̀kẹfà Osemu
àti ẹlẹ́ẹ̀keje Dafidi. 16Àwọn arábìnrin wọn ni Seruiah àti Abigaili.
Àwọn ọmọ mẹ́ta Seruiah ni Abiṣai, Joabu àti Asaheli. 17Abigaili ni ìyá Amasa, ẹni tí baba rẹ̀ sì jẹ́ Jeteri ará Iṣmaeli. 18Kalebu ọmọ Hesroni ní ọmọ láti ọ̀dọ̀ ìyàwó rẹ̀ Asuba (láti ọ̀dọ̀ Jerioti). Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ọmọ rẹ̀:
Jeṣeri, Ṣobabu àti Ardoni. 19Nígbà tí Asuba sì kú, Kalebu sì fẹ́ Efrata ní aya, ẹni tí ó bí Huri fún un.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.