1 Kronika 2:15
1 Chronicles 2:15 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
ẹlẹ́ẹ̀kẹfà Osemu àti ẹlẹ́ẹ̀keje Dafidi.
1 Chronicles 2:15 in English
1 Chronicles 2:15 · Berean Standard Bible
Ozem sixth, and David seventh.
Context
13Jese sì ni baba
Eliabu àkọ́bí rẹ̀; ọmọ ẹlẹ́ẹ̀kejì sì ni Abinadabu,
ẹlẹ́ẹ̀kẹta ni Ṣimea, 14ẹlẹ́ẹ̀kẹrin Netaneli,
ẹlẹ́ẹ̀karùnún Raddai, 15ẹlẹ́ẹ̀kẹfà Osemu
àti ẹlẹ́ẹ̀keje Dafidi. 16Àwọn arábìnrin wọn ni Seruiah àti Abigaili.
Àwọn ọmọ mẹ́ta Seruiah ni Abiṣai, Joabu àti Asaheli. 17Abigaili ni ìyá Amasa, ẹni tí baba rẹ̀ sì jẹ́ Jeteri ará Iṣmaeli.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.