1 Kronika 14:7
1 Chronicles 14:7 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Eliṣama, Beeliada, àti Elifeleti.
1 Chronicles 14:7 in English
1 Chronicles 14:7 · Berean Standard Bible
Elishama, Beeliada,* and Eliphelet.
Context
5Ibhari, Eliṣua, Elifeleti, 6Noga, Nefegi, Jafia, 7Eliṣama, Beeliada, àti Elifeleti. 8Nígbà tí àwọn ará Filistini gbọ́ pé a ti fi àmì òróró yàn Dafidi ní ọba lórí gbogbo Israẹli, wọ́n sì lọ sókè pẹ̀lú ipá láti wá a rí, ṣùgbọ́n Dafidi gbọ́ nípa rẹ̀ ó sì jáde lọ láti pàdé wọn. 9Nísinsin yìí àwọn ará Filistini ti wá láti gbógun ti àfonífojì Refaimu;
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.