1 Kronika 12:6
1 Chronicles 12:6 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Elkana, Iṣiah, Asareeli, Joeseri àti Jaṣobeamu ará Kora;
1 Chronicles 12:6 in English
1 Chronicles 12:6 · Berean Standard Bible
Elkanah, Isshiah, Azarel, Joezer, and Jashobeam, who were Korahites;
Context
4Àti Iṣmaiah ará Gibeoni, ọkùnrin alágbára kan lára àwọn ọgbọ̀n ẹni tí ó jẹ́ olórí nínú àwọn ọgbọ̀n;
Jeremiah, Jahasieli, Johanani, Josabadi ará Gedera, 5Elusai, Jerimoti, Bealiah, Ṣemariah àti Ṣefatia ará Harufiti; 6Elkana, Iṣiah, Asareeli, Joeseri àti Jaṣobeamu ará Kora; 7àti Joẹla, àti Sebadiah àwọn ọmọ Jerohamu láti Gedori. 8Díẹ̀ lára àwọn ará Gadi yà sọ́dọ̀ Dafidi ní ibi gíga ní aginjù. Wọ́n sì jẹ́ onígboyà ológun tí ó múra fún ogun tí ó sì lágbára láti di asà àti ẹṣin mú. Ojú wọn sì dàbí ojú kìnnìún, wọ́n sì yára bí àgbọ̀nrín lórí àwọn òkè.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.