1 Kronika 12:5
1 Chronicles 12:5 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Elusai, Jerimoti, Bealiah, Ṣemariah àti Ṣefatia ará Harufiti;
1 Chronicles 12:5 in English
1 Chronicles 12:5 · Berean Standard Bible
Eluzai, Jerimoth, Bealiah, Shemariah, and Shephatiah the Haruphite;
Context
3Ahieseri olórí wọn àti Joaṣi àwọn ọmọ Ṣemaah ará Gibeah:
Jeṣieli àti Peleti ọmọ Asmafeti,
Beraka, Jehu ará Anatoti. 4Àti Iṣmaiah ará Gibeoni, ọkùnrin alágbára kan lára àwọn ọgbọ̀n ẹni tí ó jẹ́ olórí nínú àwọn ọgbọ̀n;
Jeremiah, Jahasieli, Johanani, Josabadi ará Gedera, 5Elusai, Jerimoti, Bealiah, Ṣemariah àti Ṣefatia ará Harufiti; 6Elkana, Iṣiah, Asareeli, Joeseri àti Jaṣobeamu ará Kora; 7àti Joẹla, àti Sebadiah àwọn ọmọ Jerohamu láti Gedori.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.