Native Bible

1 Chronicles 11:42 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Adina ọmọ Ṣisa ará Reubeni, ẹni tí ó jẹ́ ìjòyè ará Reubeni, àti pẹ̀lú ọgbọ́n rẹ̀.

1 Chronicles 11:42 in English

1 Chronicles 11:42 · Berean Standard Bible

Adina son of Shiza the Reubenite, chief of the Reubenites, and the thirty with him,

Context

40Ira ará Itri, Garebu ará Itri, 41Uriah ará Hiti Sabadi ọmọ Ahlai. 42Adina ọmọ Ṣisa ará Reubeni, ẹni tí ó jẹ́ ìjòyè ará Reubeni, àti pẹ̀lú ọgbọ́n rẹ̀. 43Hanani ọmọ Maaka. Jehoṣafati ará Mitini. 44Ussia ará Asiterati, Ṣama àti Jeieli àwọn ọmọ Hotami ará Aroeri,

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.