Native Bible

1 Chronicles 11:44 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ussia ará Asiterati, Ṣama àti Jeieli àwọn ọmọ Hotami ará Aroeri,

1 Chronicles 11:44 in English

1 Chronicles 11:44 · Berean Standard Bible

Uzzia the Ashterathite, Shama and Jeiel the sons of Hotham the Aroerite,

Context

42Adina ọmọ Ṣisa ará Reubeni, ẹni tí ó jẹ́ ìjòyè ará Reubeni, àti pẹ̀lú ọgbọ́n rẹ̀. 43Hanani ọmọ Maaka. Jehoṣafati ará Mitini. 44Ussia ará Asiterati, Ṣama àti Jeieli àwọn ọmọ Hotami ará Aroeri, 45Jediaeli ọmọ Ṣimri, àti arákùnrin Joha ará Tisi 46Elieli ará Mahafi Jeribai àti Joṣafia àwọn ọmọ Elnaamu, Itimah ará Moabu,

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.