Native Bible

1 Chronicles 1:29 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Èyí ni àwọn ọmọ náà: Nebaioti àkọ́bí Iṣmaeli: Kedari, Adbeeli, Mibsamu,

1 Chronicles 1:29 in English

1 Chronicles 1:29 · Berean Standard Bible

These are their genealogies: Nebaioth the firstborn of Ishmael, then Kedar, Adbeel, Mibsam,

Context

27àti Abramu (tí ń ṣe Abrahamu). 28Àwọn ọmọ Abrahamu: Isaaki àti Iṣmaeli. 29Èyí ni àwọn ọmọ náà: Nebaioti àkọ́bí Iṣmaeli: Kedari, Adbeeli, Mibsamu, 30Miṣima, Duma, Massa, Hadadi, Tema, 31Jeturi, Nafiṣi, àti Kedema. Àwọn wọ̀nyí ni ọmọ Iṣmaeli.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.