Native Bible

1 Chronicles 1:28 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àwọn ọmọ Abrahamu: Isaaki àti Iṣmaeli.

1 Chronicles 1:28 in English

1 Chronicles 1:28 · Berean Standard Bible

The sons of Abraham were Isaac and Ishmael.

Context

26Serugu, Nahori, Tẹra, 27àti Abramu (tí ń ṣe Abrahamu). 28Àwọn ọmọ Abrahamu: Isaaki àti Iṣmaeli. 29Èyí ni àwọn ọmọ náà: Nebaioti àkọ́bí Iṣmaeli: Kedari, Adbeeli, Mibsamu, 30Miṣima, Duma, Massa, Hadadi, Tema,

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.