Native Bible

1 Chronicles 1:27 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

àti Abramu (tí ń ṣe Abrahamu).

1 Chronicles 1:27 in English

1 Chronicles 1:27 · Berean Standard Bible

and Abram (that is, Abraham).

Context

25Eberi, Pelegi. Reu, 26Serugu, Nahori, Tẹra, 27àti Abramu (tí ń ṣe Abrahamu). 28Àwọn ọmọ Abrahamu: Isaaki àti Iṣmaeli. 29Èyí ni àwọn ọmọ náà: Nebaioti àkọ́bí Iṣmaeli: Kedari, Adbeeli, Mibsamu,

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.