1 Kronika 1:11
1 Chronicles 1:11 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ejibiti sì bí Ludimu, Anamimu, Lehabimu, Naftuhimu,
1 Chronicles 1:11 in English
1 Chronicles 1:11 · Berean Standard Bible
Mizraim was the father of the Ludites, the Anamites, the Lehabites, the Naphtuhites,
Context
9Àwọn ọmọ Kuṣi ni:
Seba, Hafila, Sabta, Raama, àti Sabteka.
Àwọn ọmọ Raama:
Ṣeba àti Dedani. 10Kuṣi sì bí Nimrodu
ẹni tí ó di alágbára jagunjagun ní ayé. 11Ejibiti sì bí
Ludimu, Anamimu, Lehabimu, Naftuhimu, 12Patrusimu, Kasluhimu (láti ọ̀dọ̀ ẹni tí àwọn ará Filistini ti wá) àti àwọn ará Kaftorimu. 13Kenaani sì bí Sidoni àkọ́bí rẹ̀,
àti Heti,
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.